Málákì 4:4-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. “Ẹ rántí òfin Mósè ìránṣẹ́ mi, àwọn ìlànà àti òfin èyí tí mo fún un ní Hórébù fún gbogbo Ísírẹ́lì.”

5. “Wò ó, èmi yóò rán wòlíì Èlíjà sí i yín, ki ọjọ́ ńlá, ọjọ́ ẹ̀rù Olúwa to dé:

6. Òun yóò sì pa ọkàn àwọn baba dà sí ti àwọn ọmọ, àti ọkàn àwọn ọmọ sì ti àwọn baba wọn, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, èmi yóò wá, èmi yóò sì fi ilẹ̀ náà gégùn-ún.”

Málákì 4