48. Níbi ti“ ‘kòkòrò wọn kìí kú,,tí iná kì í sì í kú.’
49. Níbẹ̀ ni a ó ti fi iná dán ẹnìkọ̀ọ̀kan wò
50. “Iyọ̀ dára, ṣùgbọ́n tí ó bá sọ agbára adùn rẹ̀ nù, báwo ni ẹ ṣè lè padà mu un dùn? Ẹ ni iyọ̀ nínú ara yín, ki ẹ sì máa gbé ni àlàáfíà pẹ̀lú ara yín.”