Lúùkù 1:45-47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

45. Alábùkúnfún sì ni ẹni tí ó gbàgbọ́: nítorí nǹkan wọ̀nyí tí a ti sọ fún un láti ọ̀dọ̀ Olúwa wá yóò ṣẹ.”

46. Màríà sì dáhùn, ó ní:“Ọkàn mi yin Olúwa lógo,

47. Ẹ̀mí mi sì yọ̀ sí Ọlọ́run Olùgbàlà mi.

Lúùkù 1