Léfítíkù 21:22-24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Ó lè jẹ́ oúnjẹ Ọlọ́run rẹ̀ tàbí èyí tí ó mọ́ jùlọ ṣùgbọ́n torí pé ó ní àbùkù kò gbọdọ̀ sún mọ́ ibi aṣọ títa tàbí pẹpẹ.

23. Nípa ṣíṣe bẹ́ẹ̀ yóò ba ibi mímọ́ mi jẹ́ torí pé, Èmi Olúwa ló ti sọ wọ́n di mímọ́.’ ”

24. Wọ̀nyí ni àwọn ohun tí Mósè sọ fún Árónì, àwọn ọmọ Árónì àti gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì.

Léfítíkù 21