Jóṣúà 2:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà náà ni Jóṣúà ọmọ Núnì rán àwọn ayọ́lẹ̀wò méjì jáde ní àsírí láti Ṣítímù. Ó sì wí pé, “Ẹ lọ wo ilẹ̀ náà, pàápàá Jẹ́ríkò.” Wọ́n sì lọ, wọ́n wọ ilé aṣẹ́wó kan, tí à ń pè ní Ráhábù, wọ́n sì dúró síbẹ̀.

2. A sì sọ fún ọba Jẹ́ríkò, “Wò ó! Àwọn ará Ísírẹ́lì kan wá ibí ní alẹ́ yìí láti wá yọ́ ilẹ̀ yí wò.”

Jóṣúà 2