Jóṣúà 19:2-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Lára ìpín wọn ní:Béérí Ṣébà (tàbí Ṣẹ́bà), Móládà,

3. Hasari-Ṣúálì, Báláhì, Ésémù,

4. Élítóládì, Bétúlì, Hómà,

5. síkílágì, Bẹti-Mákábótì, Hasari-Súsà,

6. Bẹti-Lébà ati Ṣárúẹ́nì, ìlú wọn jẹ́ mẹ́talá àti ìletò wọn.

7. Háínì, Rímónì, Étérì àti Áṣánì: Ìlú wọn jẹ́ mẹ́rin àti ìletò wọn:

8. Àti gbogbo àwọn agbégbé ìlú wọ̀nyí títí dé Baalati-Béérì (Rámà ní Négéfì).Èyí ni ìní àwọn ọmọ Símíónì, agbo ilé, ní agbo ilé.

Jóṣúà 19