Jóṣúà 19:15-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Lára wọn ni Kátatì, Náhalálì, Símírónì, Ìdálà àti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù. Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlá àti ìletò wọn.

16. Ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn jẹ́ ìní Sébúlunì, ní agbo ilé agbo ilé.

17. Gègé kẹrin jáde fún Ísákárì, agbo ilé ní agbo ilé.

18. Lára ilẹ̀ wọn ni èyí:Jésíréélì, Késúlótì, Súnemù,

Jóṣúà 19