Jóṣúà 15:51-54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

51. Gósénì, Hólónì àti Gílónì, ìlú mọ́kànlá àti ìletò wọn.

52. Árabù, Dúmà, ṣ Éṣánì,

53. Jánímù, Bẹti-Tápúà, Áfékà,

54. Húmútà, Kíríátì Áríbà (tí í se, Hébúrónì) àti Síori: ìlú mẹ́sàn án àti àwọn ìletò rẹ̀

Jóṣúà 15