Jóṣúà 14:13-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Bẹ́ẹ̀ ni Joṣua súre fun Kélẹ́bù ọmọ Jéfún ó si fun un ní Hébúrónì ni ilẹ̀ ìni

14. Bẹ́ẹ̀ ni Hébúrónì jẹ́ ti Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè ará Kánísì láti ìgbà náà, nítorí tí ó tẹ̀lé Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì tọkàntọkàn.

15. (Hébúrónì a sì máa jẹ́ Kíríàtì Áríbà ní ẹ̀yìn Áríbà, èyí tí ó jẹ́ ènìyàn ńlá nínú àwọn ọmọ Ánákì.)Nígbà náà ni ilẹ̀ náà sinmi ogun.

Jóṣúà 14