Jóòbù 34:24-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Òun ó sì fọ́ àwọn alágbáratúútúú láìní ìwádìí, a sì fi ẹlòmìíràn dípò wọn,

25. nítorí pé ó mọ iṣẹ́ wọn, ó sì yíwọn po ní òru; bẹ́ẹ̀ ni wọ́n di ìtẹ́rẹ́ pọ̀.

26. Ó kọlù wọ́n nítorí ìwàbúburú wọn níbi tí àwọn ẹlòmìíràn rí i,

27. nítorí pé wọ́n padà sẹ́yìndà sí i,wọn kò sì fi yè sí ipa ọ̀nà rẹ̀ gbogbo,

28. kí wọn kí ó sì mú igbe ẹkúnàwọn tálákà lọ dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, òunsì gbọ́ igbe ẹkún aláìní

Jóòbù 34