Jóòbù 30:16-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. “Àti nísinsin yìí ọkàn mí sì dà jádesíi; ọjọ́ ìpọ́njú mi dì mí mú.

17. Òru gún mi nínú egungun mi, ìyítí ó bù mí jẹ kò sì sinmi.

18. Nípa agbára ńlá rẹ̀ Ọlọ́run wà bí aṣọ ìbora fún mi, ó sì lẹ̀mọ́mi ní ara yíká bí ọrùn aṣọ ìlekè mi.

Jóòbù 30