Jóòbù 24:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Wọ́n á sì dà kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ aláìní babalọ, wọ́n a sì gba ọ̀dá-màlúù opó ní ohun ògo.

4. Wọ́n á bi aláìní kúrò lójú ọ̀nà,àwọn talákà àyé a sá pamọ́ pọ̀.

5. Kíyèsí i, bí i kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ìgbẹ́ nínú ijùni àwọn talákà ijáde lọ sí iṣẹ́wọn; Wọ́n a tètè dìde láti wáohun ọdẹ; ijù pèsè oúnjẹ fúnwọn àti fún àwọn ọmọ wọn

Jóòbù 24