Jóòbù 22:28-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

28. Ìwọ ó sì gbìmọ̀ ohun kan pẹ̀lú,yóò sì fi ìdí múlẹ̀ fún ọ; ìmọ́lẹ̀ yóò sì mọ́ sípa ọ̀nà rẹ.

29. Nígbà tí ipa-ọ̀nà rẹ bá lọ sísàlẹ̀,nígbà náà ni ìwọ o wí pé, ‘Ìgbésókè ń bẹ!’Ọlọ́run yóò sì gba onírẹ̀lẹ̀ là!

30. Yóò gba ẹni tí kì í iṣe aláìjẹ̀bi là,a ó sì gbà á nípa mímọ́ ọwọ́ rẹ̀.”

Jóòbù 22