Jòhánù 5:45-47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

45. “Ẹ má ṣe rò pé, èmi ó fi yín sùn lọ́dọ̀ Baba: ẹni tí ń fi yín sùn wà, àní Mósè, ẹni tí ẹ̀yin gbẹ́kẹ̀lẹ́.

46. Nítorí pé ẹ̀yin ìbá gba Mósè gbọ́, ẹ̀yin ìbá gbà mí gbọ́: nítorí ó kọ ìwé nípa tẹ̀mi.

47. Ṣùgbọ́n bí ẹ̀yin kò bá gba ìwé rẹ̀ gbọ́, ẹ̀yin ó ti ṣe gbà ọ̀rọ̀ mi gbọ́?”

Jòhánù 5