Jòhánù 4:53-54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

53. Bẹ́ẹ̀ ni baba náà mọ̀ pé ọmọ rẹ̀ yè: Òun tìkara rẹ̀ sì gbàgbọ́, àti gbogbo ilé rẹ̀.

54. Èyí ni iṣẹ́ àmì kéjì tí Jésù ṣe nígbà tí ó ti Jùdéà jáde wá sí Gálílì.

Jòhánù 4