Jeremáyà 48:12-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. Ṣùgbọ́n ọjọ́ ń bọ̀,”ni Olúwa wí,“nígbà tí n ó rán àwọn tí ó da ọtí láti inú àwọn ìgòtí wọ́n ó sì dà á síta;Wọn ó sọ àwọn ìgò rẹ̀ di òfo,wọn ó sì fọ́ àwọn ife rẹ̀.

13. Nígbà náà Móábù yóò sì tú u nítorí kémósì,bí ojú ti í ti ilé Ísírẹ́lìnígbà tí ó gbẹ́kẹ̀lé Bétélì.

14. “Báwo ni o ṣe lè sọ pé, ‘ajagun ni wá,alágbára ní ogun jíjà’?

Jeremáyà 48