Jẹ́nẹ́sísì 36:41-43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

41. Ohólíbámà, Élà, Pínónì,

42. Kénásì, Témáínì Míbísárì,

43. Mágídíélì, àti Írámù. Àwọn wọ̀nyí ni olóyè Édómù, gẹ́gẹ́ bí wọn ti tẹ̀dó sí ilẹ̀ tí wọ́n gbà.Èyí ni Ísọ̀ baba àwọn ará Édómù.

Jẹ́nẹ́sísì 36