Jẹ́nẹ́sísì 36:25-29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

25. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Ánà:Dísónì àti Óhólíbámà (Àwọn ọmọbìnrin ni wọn).

26. Àwọn ọmọ Dísónì ni:Hémídánì, Ésíbánì, Ítíránì àti Kéránì.

27. Àwọn ọmọ Éṣérì:Bílíhánì, Ṣááfánì, àti Ákánì.

28. Àwọn ọmọ Díṣánì ni Húsì àti Áránì.

29. Àwọn wọ̀nyí ni olórí ìdílé Hórì:Lótanì, Ṣóbálì, Ṣíbéónì, Áná,

Jẹ́nẹ́sísì 36