Jẹ́nẹ́sísì 10:12-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. àti Résínì, tí ó wà ní àárin Nínéfè àti Kálà, tí ó jẹ́ ìlú olókìkí.

13. Mísíráímù ni baba ńlá àwọn aráLúdì, Ánámì, Léhábì, Náfítúhímù.

14. Pátírúsímù, Kásílúhímù (èyí tí í ṣe baba ńlá àwọn Fílístínì) àti Káfítórímù.

15. Kénánì ni baba àwọn aráSídónì (èyi ni àkọ́bí rẹ̀), àti àwọn ara Hítì.

16. Àwọn ará Jébúsì, Ámórì, Gágásì.

17. Hífì, Áríkì, Sínì,

18. Áfádì, Ṣémárì àti Hámátì.Nígbà tí ó ṣe, àwọn ẹ̀yà Kénánì tàn kálẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 10