Jẹ́nẹ́sísì 1:18-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

18. láti ṣàkóso ọ̀sán àti òru àti láti pààlà sí àárin ìmọ́lẹ̀ àti òkùnkùn: Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.

19. Àsálẹ́ àti òwúrọ jẹ́ ọjọ́ kẹrin.

20. Ọlọ́run sì wí pé, “Jẹ́ kí omi kí ó kún fún àwọn ohun alààyè, kí àwọn ẹyẹ kí ó sì máa fò ní òfuurufú.”

Jẹ́nẹ́sísì 1