Ìfihàn 20:14-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. Àti ikú àti ipò-òkú ni a sì sọ sínú adágún iná. Èyí ni ikú kejì.

15. Bí a bá sì rí ẹnikẹ́ni tí a kò kọ orúkọ rẹ̀ sínú ìwé ìyè, a ó sọ ọ́ sínú adágún iná.

Ìfihàn 20