Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:42-43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

42. Èyí sì di mímọ̀ já gbogbo Jópà; ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì gba Olúwa gbọ́.

43. Ó gbé ọjọ́ púpọ̀ ni Jópà ní ọ̀dọ̀ ọkùnrin kan Símónì oníṣọ̀nà-awọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9