Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Lẹ́yìn ọjọ́ méta tí ó dé sí ilẹ̀ náà, Fésítúsì gòkè láti Kesaríà lọ sì Jerúsálémù,

2. ní ibi tí àwọn olórí àlùfáà àti àwọn ènìyàn pàtàkì nínú àwọn Júù ti gbé ẹ̀sùn tí wọ́n fi kan Pọ́ọ̀lù wá síwájú rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25