Hósíà 6:10-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Mo ti rí ohun tó bani lẹ́rùní ilé Ísírẹ́lì.Níbẹ̀ Éfúráímù, fi ara rẹ̀ fún àgbèrèÍsírẹ́lì sì di aláìmọ́.

11. “Àti fún ìwọ, JúdàA ti yan ọjọ́ pẹ̀lú ìkórè rẹ“Nígbà tí mo bá fẹ́ dá ohun ìní àwọn ènìyàn mi padà,

Hósíà 6