Hósíà 13:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà Éfúráímù bá ń ṣọ̀rọ̀, àwọn ènìyàn máa ń wárìrì,a gbé e ga ní Ísírẹ́lìṣùgbọ́n ó jẹ̀bi ẹ̀ṣùn pé ó ń sin òrìṣà Báálì, ó sì kú.

2. Báyìí, wọ́n ń dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀wọn fi fàdákà ṣe ère òrìṣà fúnra wọnère tí a fi ọgbọ́n dá àrà sígbogbo wọn jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ oníṣọ̀nàWọn ń sọ nípa àwọn ènìyànwọ̀nyí. Pé, Jẹ́ kí àwọn“Ènìyàn tí ń rúbọ fi ẹnuko àwọn màluu ni ẹnu.”

Hósíà 13