Ẹ́sírà 10:33-43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

33. Nínú àwọn ìran Hásíúmù:Mátíténáì, Mátítatítayà, Ṣábádì, Élífélétì, Jérémáì, Mánásè àti Ṣíméhì.

34. Nínú àwọn ìran Bánì:Máádáì, Ámírámù, Úélì,

35. Bénáíáyà, Bédéíáyà, Kélúhì,

36. Fáníyà, Mérémótì, Élíásíbù,

37. Mátítamáyà, Mátíténáì àti Jáásù.

38. Nínú àwọn ìran Bínúì:Ṣíméhì,

39. Ṣélémíáyà, Nátanì, Ádáyà,

40. Mákánádébáì, Ṣásíáì, Ṣáráì,

41. Ásárélì, Ṣélémíáyà, Ṣémáríàyà,

42. Ṣálílúmì, Ámáríyà àti Jóṣẹ́fù.

43. Nínú àwọn ìran Nébò:Jérélì, Mátítaíyà, Ṣábádì, Ṣábínà, Jádáì, Jóélì àti Bénáíáyà.

Ẹ́sírà 10