1. Báwo ni Olúwa ṣe bo ọmọbìnrin Síónìpẹ̀lú ìkúùkù ìbínú rẹ̀!Ó sọ ògo Ísírẹ́lì kalẹ̀Láti ọ̀run sí ayé;kò rántí àpótí-ìtìṣẹ̀ rẹ̀ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀.
2. Làìní àánú ni Olúwa gbéibùgbé Jákọ́bù mì;nínú ìrunú rẹ̀ ni ó wóibi gíga ọmọbìnrin Júdà lulẹ̀.Ó ti mú ìjọba àti àwọn ọmọ aládé ọkùnrinlọ sínú ilẹ̀ ní àìlọ́wọ̀.