Ékísódù 18:26-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. Wọ́n sì ń ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn ní ìgbà gbogbo. Wọ́n sì ń mú ẹjọ́ tó le tọ Mósè wá; ṣùgbọ́n wọ́n ń dá ẹjọ́ tí kò le fún rawọn

27. Mósè sì jẹ́ kí àna rẹ̀ lọ ní ọ̀nà rẹ̀, Jẹ́tírò sì padà sí ilẹ̀ ẹ rẹ̀.

Ékísódù 18