Deutarónómì 3:28-29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

28. Ṣùgbọ́n yan Jósúà, kí o sì gbà á níyànjú, mú un lọ́kàn le, torí pé òun ni yóò ṣíwájú àwọn ènìyàn wọ̀nyí kọjá, yóò sì jẹ́ kí wọn jogún ilẹ̀ náà tí ìwọ yóò rí.”

29. Báyi ni a dúró ní àfonífojì ní ẹ̀bá Bétí-Péórì.

Deutarónómì 3