Àwọn Hébérù 11:39-40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

39. Gbogbo àwọn wọ̀nyí tí a jẹ́ri rere sí nípa ìgbàgbọ́, wọn kò sì rí ìlérí náà gbà:

40. Nítorí Ọlọ́run ti pèsè ohun tí o dárajù sílẹ̀ fún wa, pé láìsí wa, kí a má ṣe wọn pé.

Àwọn Hébérù 11