Ámósì 9:9-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. “Nítorí Èmi yóò pàṣẹ,Èmi yóò sì mi ilé Ísírẹ́lìní àárin àwọn orílẹ̀ èdèbí a ti ń jọ ọkàn nínú ajọ̀tí hóró kín ń kín kì yóò bọ́ sórí ilẹ̀.

10. Gbogbo àwọn ẹlẹ́sẹ̀ láàrin àwọn ènìyàn mini yóò ti ipa idà kúgbogbo àwọn ti ń wí péAburú kì yóò lé wa bá,bẹ́ẹ̀ ni kì yóò ká wa mọ́?A mú Ísírẹ́lì padà bọ̀ sípò.

11. “Ní ọjọ́ náà ní Èmi yóò gbéàgọ́ Dáfídì tí ó wó róÈmi yóò mọ odi rẹ̀ tí ó wóÈmi yóò sì sọ ahoro rẹ̀ di ìlúÈmi yóò sì kọ bí ó ti wà tẹ́lẹ̀

Ámósì 9