Àìsáyà 34:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Idà Olúwa kún fún ẹ̀jẹ̀a mú un ṣanra fún ọ̀rá,àti fún ẹ̀jẹ̀ ọ̀dọ́-agùtàn àti ewurẹ,fún ọ̀rá iwe àgbò—nítorí Olúwa ni ìrúbọ kan ní Bósírà,àti ìpakúpa ńlá kan ní ilẹ̀ Édómù.

7. Àti àwọn àgbáǹréré yóòba wọn ṣọ̀kalẹ̀ wá,àti àwọn ẹgbọ̀rọ̀ màlúùpẹ̀lú àwọn akọ màlúù,ilé wọn ni a ó fi ẹ̀jẹ̀ rin,a ó si fi ọ̀rá sọ ekuru wọn di Ọlọ́ràá.

8. Nítorí ọjọ́ ẹ̀san Olúwa ni,àti ọdún ìsanpadà,nítorí ọ̀ràn Ṣíhónì.

Àìsáyà 34