Àìsáyà 28:27-29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

27. A kì í fi òòlù pa káráwétàbí kẹ̀kẹ́-ẹrù là á fi yí kúmínì mọ́lẹ̀;ọ̀pá ni a fi ń lu káráwé,àti kúmínì pẹ̀lú igi.

28. A gbọdọ̀ lọ hóró kí a tó ṣe àkàrà;bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan kì í máa pa á lọ títí láé.Bí ó tilẹ̀ yí ẹṣẹ̀ kẹ̀kẹ́ ìpakà a rẹ̀ lóríi rẹ̀,àwọn ẹṣin rẹ̀ kò le lọ̀ ọ́.

29. Gbogbo èyí pẹ̀lú ti ọ̀dọ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun wá,oníyanu ní ìmọ̀ràn àti ológo ní ọgbọ́n.

Àìsáyà 28