Àìsáyà 21:16-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún mi: “Láàrin ọdún kan, gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀fà tí ó wà lábẹ́ ọgbà, í ti í kà á, gbogbo ayẹkẹ Kédárì yóò wá sí òpin.

17. Àwọn tafàtafà tí ó ṣálà, àwọn jagunjagun Kédárì kò ní tó nǹkan” Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì ni ó ti sọ̀rọ̀.

Àìsáyà 21