2 Sámúẹ́lì 23:37-39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

37. Sélékì ará Ámónì,Náhárì ará Béérótì, ẹni tí ń ru ìhámọ́ra Jóábù ọmọ Sérúíà;

38. Írà ará Játírì,Gárébù ará Játírì.

39. Ùráyà ará Hítì.Gbogbo wọn jẹ́ mẹ́tadínlógójì.

2 Sámúẹ́lì 23