2 Kọ́ríńtì 6:11-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Ẹ̀yin ará Kọ́ríńtì, a ti bá yín sọ òtítọ́ ọ̀rọ̀, a ṣí ọkàn wa payá sí yín.

12. A kò ni yín lára nítorí wa, ṣùgbọ́n a ni yín lára nítorí ìfẹ́ ọkàn ẹ̀yin fúnra yín.

13. Ní sísán padà, ní ọ̀nà tí ó dára, (èmi ń sọ bí ẹni pé fún àwọn ọmọdé) ẹ̀yin náà, ẹ ṣí ọkàn yín payá pẹ̀lú.

2 Kọ́ríńtì 6