2 Kíróníkà 13:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní ọdún kejìdínlógún ìjọba Jéróbóámù, Ábíjà di ọba Júdà.

2. Ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mẹ́ta. Orúkọ ìyá rẹ̀ a máa jẹ́ Mákà, ọmọbìnrin Úríélì ti Gíbéà.Ogun wà láàárin Ábíjà àti Jéróbóámù.

2 Kíróníkà 13