1 Tẹsalóníkà 5:24-26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Olótítọ́ ni ẹni tí ó pè yín, yóò sì ṣe.

25. Ẹ̀yin ará, ẹ gbàdúrà fún wa.

26. Ẹ gbà ara yín ní ọwọ́ ní orúkọ mi pẹ̀lú ọkàn funfun.

1 Tẹsalóníkà 5