1 Sámúẹ́lì 27:11-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Dáfídì kò sì dá ọkùnrin tàbí obìnrin sí láàyè, láti mú ìròyìn wá sí Gátì, wí pé, “Ki wọn máa bá à sọ ọ̀rọ̀ wa nibẹ̀, pé, ‘Báyìí ni Dáfídì ṣe’ ” Àti bẹ́ẹ̀ ni iṣe rẹ̀ yóò sì rí ni gbogbo ọjọ́ ti yóò fí jókòó ni ìlú àwọn Fílístínì.

12. Ákíṣì sì gba ti Dáfídì gbọ́, wí pé, “Òun ti mú kí Ísírẹ́lì àti àwọn ènìyàn rẹ̀ kóríra rẹ̀ pátapáta, yóò si jẹ́ ìránṣẹ́ mi títí láé.”

1 Sámúẹ́lì 27