1 Kọ́ríńtì 15:41-43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

41. Ọ̀tọ̀ ni ògo ti òòrùn, ọ̀tọ̀ ni ògo ti òṣùpá, ọ̀tọ̀ sì ni ògo ti ìràwọ̀; ìràwọ̀ sá yàtọ̀ sí ìràwọ̀ ni ògo.

42. Gẹ́gẹ́ bẹ́ẹ̀ sí ni àjíǹde òkú. A gbìn ín ní ìdibàjẹ́; a sí jì í didé ni àìdíbàjẹ́:

43. A gbìn ín ni àìní ọlá, a sí jí i dìde ni ògo; a gbìn ín ni àìlera, a sì ji í dìde ní agbára.

1 Kọ́ríńtì 15