1 Kíróníkà 6:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Àwọn ọmọ Léfì:Gérísónì, Kóhátì àti Mérárì.

2. Àwọn ọmọ Kóhátì:Ámírámù, Ísárì, Hébírónì, àti Húsíélì.

1 Kíróníkà 6