1 Kíróníkà 2:10-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Rámù sì ni babaÁmínádábù, àti Ámínádábù baba Náṣónì olórí àwọn ènìyàn Júdà.

11. Náṣónì sì ni baba Sálímà, Sálímà ni baba Bóásì,

12. Bóásì baba Óbédì àti Óbédì baba Jésè.

1 Kíróníkà 2