36. Héférì ará Mékérátì,Áhíjà ará Pélónì,
37. Hésírónì ará KárímélìNáráì ọmọ Ésíbáì,
38. Jóẹ́lì arákùnrin NátanìMíbárì ọmọ Hágárì,
39. Ṣélékì ará Ámónì,Náháráì ará Bérótì ẹni tí ó jẹ́ áru ìhámọ́ra Jóábù ọmọ Ṣérúyà.
40. Írà ará Ítírì,Gárébù ará Ítírì,
41. Húríyà ará HítìṢábádì ọmọ Áháláyì.
42. Ádínà ọmọ Ṣísà ará Réúbẹ́nì, ẹni tí ó jẹ́ ìjòyè ará Réubẹ́nì, àti pẹ̀lú ọgbọ́n Rẹ̀.
43. Hánánì ọmọ Mákà.Jóṣáfátì ará Mítínì.