35. Àwọn ọmọ Ísọ̀:Élífásì, Réuélì, Jéúsì, Jálámù, àti Kórà.
36. Àwọn ọmọ Élífásì:Témánì, Ómárì, Ṣéfì, Gátamù àti Kénásì;làti Tímánà: Ámálékì.
37. Àwọn ọmọ Réúélì:Náhátì, Ṣérà, Ṣámà àti Mísà.
38. Àwọn ọmọ Ṣéírì:Lótanì, Ṣóbálì, Ṣíbéónì, Ánà, Díṣónì, Ésárì àti Dísánì.