30. Míṣímà, Dúmà, Másà, Hádádì, Témà,
31. Jétúrì, Náfísì, àti Kédámù. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Íṣímáẹ́lì
32. Àwọn ọmọ Kétúrà, obìnrin Ábúráhámù:Símíránì, Jókíṣánì Médánì, Mídíánì Iṣíbákì àti Ṣúà.Àwọn ọmọ Jókísánì:Ṣébà àti Dédánì.
33. Ọmọ Mídíánì:Éfà. Hénókì, Éférì, Ábídà àti Élídà.Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ìran Kétúrà.
34. Ábúráhámù sì jẹ́ baba Ísáákì:Àwọn ọmọ Ísáákì:Ísọ̀ àti Ísírẹ́lì.
35. Àwọn ọmọ Ísọ̀:Élífásì, Réuélì, Jéúsì, Jálámù, àti Kórà.
36. Àwọn ọmọ Élífásì:Témánì, Ómárì, Ṣéfì, Gátamù àti Kénásì;làti Tímánà: Ámálékì.